E MÓ F’ENU BA ÌPÍNLÈ RIVERS JÉ! GÓMÌNÀ FÚBÀRÁ KÌLÒ
Gómìnà ìpínlè Rivers, Alàgbà Fubara ti sopé gbogbo àwon ti
OPE O! NIGERIA SA SOUTH AFRICA LEPA LATI PEREGEDE FUN ASEKAGBA AFCON
Oju ti Patrice Motsepe Alaga CAF bi Super Eagles se ja pantie fun Bafana Bafana leyin orisirisi ojoro
E MO WE OHUN TI KII SE TIWA MOWA LORUN O! AARE TINUBU KO LO FE LO OKO OJU OMI – AMUGBALEGBE AARE
Amugbalegbe Aare ni Omoogun Ori omi NAijiria lo fe ra oko oju omi onifaaji, kii se Aare Tinubu
LOBATAN! ILE EJO DA ILE ASOFIN IPINLE RIVERS LOWOKO LATI RO GOMINA FUBARA NIPO
ile ejo se idalowoko fun akitiyan lati yo Gomina Fubara nipo.
ÌYANU ŃLÁ BÍ ÀGÀN ODÚN MÉÈDÓGBÒN SE BI ỌMỌ MẸSAN-AN LEKANSOSO
Obinrin àgàn olójó-pípé bí ọmọ mẹsan leekansoso
LÓBÁTÁN! ỌMỌ OYEDEPO JÁ ÌJỌ BABA RE SÓLÓPÓN LÁTI DÁ ÌJỌ ARA RÈ SÍLÈ
Ọmọ Bísòbù Oyedepo ja ìjọ bàbá è sólópón
ÌJỌBA MI YÓÒ MÚ ỌDÚN ÌBEJÌ TI IGBÓ-ORÀ GBÒÒRÒ SII.
Gomina Seyi Makinde ṣèlérí ìgbélárugẹ fún ọdún ibojì ni Igbo-Ora
IKÚ NI BÍ ẸNIKẸNI BÁ DÁ OJÚ IRIN RÉLÙWÉÈ ÌGBÀLÓDÉ ONÍNÁ ÈLÉŃTÍRÍKÌ KOJA! ÌJỌBA ÌPÍNLÈ ÈKÓ TÚN KÉ TANTAN BI WON SE KEDE AFIKUN IYE ÌGBÀ TÍ OKO OUN N RIN LATI MARINA SI MILE 12
Ìjọba Ìpínlẹ̀ Ekó tún ikilo se pe ki ẹnikẹ́ni maa se sun mo tabi da oju ona reluwe ìgbàlódé koja bi won ṣe kede àfikún iye ìgbà tí reluwe ìgbàlódé oníná èléńtíríkì yóò máa rìn laarin Marina sì Mile 2.