IKÚ NI BÍ ẸNIKẸNI BÁ DÁ OJÚ IRIN RÉLÙWÉÈ ÌGBÀLÓDÉ ONÍNÁ ÈLÉŃTÍRÍKÌ KOJA! ÌJỌBA ÌPÍNLÈ ÈKÓ TÚN KÉ TANTAN BI WON SE KEDE AFIKUN IYE ÌGBÀ TÍ OKO OUN N RIN LATI MARINA SI MILE 12
Ìjọba Ìpínlẹ̀ Ekó tún ikilo se pe ki ẹnikẹ́ni maa se sun mo tabi da oju ona reluwe ìgbàlódé koja bi won ṣe kede àfikún iye ìgbà tí reluwe ìgbàlódé oníná èléńtíríkì yóò máa rìn laarin Marina sì Mile 2.