ÀWỌN ỌMỌ YORÙBÁ ÀTÀTÀ MÉJÌ TÍ WỌN Ń DÁ BÍRÀ NÍ ÈKA ÈTÒ ÌJỌBA TÓ N MÓJÚTÓ KÁTÀKÁRÀ ÒUN ORÒ AJÉ NINU ÌSÈJỌBAm ILE AMẸ́RÍKÀ ATI UK
Àwọn ọmọ Ilé Yoruba ataata meji ti wọn ń ṣe bebe ni ipo Aláṣẹ ilé Amerika àti UK ni abaala kátàkárà ati ọrọ ajé àti àpò ikowopamosi ijoba.